Jobu 15:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹnu rẹ ni ó dá ọ lẹ́bi, kì í ṣe èmi;ẹ̀rí tí ò ń jẹ́ nípa rẹ ní ń ta kò ọ́.

Jobu 15

Jobu 15:1-10