Jobu 13:26-28 BIBELI MIMỌ (BM)

26. O ti kọ àkọsílẹ̀ burúkú nípa mi,o mú mi jìyà ẹ̀ṣẹ̀ ìgbà èwe mi.

27. O kó ṣẹ́kẹ́ṣẹkẹ̀ sí mi lẹ́sẹ̀,ò ń ṣọ́ ìrìn ẹsẹ̀ mi,o sì pa ààlà tí n kò gbọdọ̀ rékọjá.

28. Eniyan ń ṣègbé lọ bí ohun tí ó ń jẹrà,bí aṣọ tí ikán ti mu.

Jobu 13