Jobu 13:18-20 BIBELI MIMỌ (BM)

18. Wò ó, mo ti múra ẹjọ́ mi sílẹ̀;mo sì mọ̀ pé n óo gba ìdáláre.

19. Ta ni yóo wá bá mi rojọ́?Bí ó bá wá, n óo dákẹ́, n óo sì kú.

20. Nǹkan meji péré ni mo fẹ́ kí o ṣe fún mi,n kò sì ní farapamọ́ fún ọ:

Jobu 13