Jobu 11:19-20 BIBELI MIMỌ (BM)

19. O óo sùn, láìsí ìdágìrì,ọpọlọpọ eniyan ni wọn óo sì máa wá ojurere rẹ.

20. Àwọn ẹni ibi óo pòfo;gbogbo ọ̀nà tí wọ́n lè gbà sá àsálàni yóo parẹ́ mọ́ wọn lójú,ikú ni yóo sì jẹ́ ìrètí wọn.”

Jobu 11