Jobu 10:18-20 BIBELI MIMỌ (BM)

18. “Kí ló dé tí o fi mú mi jáde láti inú ìyá mi?Ìbá sàn kí n ti kú,kí ẹnikẹ́ni tó rí mi.

19. Wọn ìbá má bí mi rárá,kí wọ́n gbé mi láti inú ìyá mi lọ sinu ibojì.

20. Ṣebí ọjọ́ díẹ̀ ni mo níláti lò láyé?Fi mí sílẹ̀ kí n lè ní ìtura díẹ̀,

Jobu 10