Jeremaya 8:21-22 BIBELI MIMỌ (BM)

21. Nítorí ọgbẹ́ àwọn eniyan mi ni ọkàn mi ṣe gbọgbẹ́.Mò ń ṣọ̀fọ̀, ìdààmú sì bá mi.

22. Ṣé kò sí ìwọ̀ra ní Gileadi ni?Àbí kò sí oníwòsàn níbẹ̀?Kí ló dé tí àìsàn àwọn eniyan mi kò sàn?

Jeremaya 8