Jeremaya 8:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn kò wẹ egbò àwọn eniyan mi jinná,wọ́n ń kígbe pé, ‘Alaafia ni, alaafia ni,’bẹ́ẹ̀ sì ni kò sí alaafia.

Jeremaya 8

Jeremaya 8:10-19