Jeremaya 6:18 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní, “Nítorí náà, ẹ gbọ́, ẹ̀yin orílẹ̀-èdè,kí ẹ̀yin eniyan sì mọ ohun tí yóo ṣẹlẹ̀ sí wọn.

Jeremaya 6

Jeremaya 6:9-19