Jeremaya 50:35 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní,“Idà ni yóo pa àwọn ará Kalidea,idà ni yóo pa àwọn ará Babiloni,ati àwọn ìjòyè wọn,ati àwọn amòye wọn!

Jeremaya 50

Jeremaya 50:27-45