Jeremaya 45:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ọ̀rọ̀ tí Jeremaya wolii sọ fún Baruku ọmọ Neraya nìyí, ní ọdún kẹrin tí Jehoiakimu, ọmọ Josaya, jọba ní Juda. Baruku ń kọ ohun tí Jeremaya ń sọ sílẹ̀ bí Jeremaya tí ń sọ̀rọ̀.

2. Ó ní: “OLUWA Ọlọrun Israẹli sọ fún ìwọ Baruku pé,

Jeremaya 45