Jeremaya 32:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà èmi OLUWA ni mo sọ pé, n óo fi ìlú yìí lé àwọn ará Kalidea ati Nebukadinesari, ọba Babiloni lọ́wọ́, yóo sì gbà á.

Jeremaya 32

Jeremaya 32:20-38