Jeremaya 26:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó sọ gbogbo ohun tí OLUWA pa láṣẹ fún un pé kí ó sọ fún gbogbo àwọn eniyan náà tán, gbogbo wọn rá a mú, wọ́n ní, “Kíkú ni o óo kú!

Jeremaya 26

Jeremaya 26:1-16