Jeremaya 22:7 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo kó àwọn apanirun tí yóo pa ọ́ run wá,olukuluku yóo wá pẹlu ohun ìjà rẹ̀.Wọn óo gé àwọn tí wọn dára jùlọ ninu àwọn igi Kedari yín,wọn óo sì sun wọ́n níná.

Jeremaya 22

Jeremaya 22:2-8