Jeremaya 22:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ègbé ni fún ẹni tí ó wí pé,“N óo kọ́ ilé ńlá fún ara mi,ilé tí ó ní yàrá ńláńlá lókè rẹ̀.”Ó bá yọ àwọn fèrèsé sí i lẹ́gbẹ̀ẹ́.Ó fi igi kedari bo ara ògiri rẹ̀,ó wá fi ọ̀dà pupa kùn ún.

Jeremaya 22

Jeremaya 22:8-20