Jeremaya 21:6 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo fi àjàkálẹ̀ àrùn ńlá kọlu àwọn ará ìlú yìí, ati eniyan ati ẹranko ni yóo sì kú.

Jeremaya 21

Jeremaya 21:1-11