Jeremaya 18:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìkòkò tí ó ń fi amọ̀ mọ bàjẹ́ lọ́wọ́ rẹ̀, ó bá fi amọ̀ náà mọ ìkòkò mìíràn, tí ó wù ú.

Jeremaya 18

Jeremaya 18:2-6