Jẹnẹsisi 8:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Kó gbogbo ẹ̀dá alààyè tí ó wà pẹlu rẹ jáde, àwọn ẹyẹ, ẹranko ati àwọn ohun tí ń fàyà fà lórí ilẹ̀, kí wọ́n lè máa bímọ lémọ, kí wọ́n sì pọ̀ sí i lórí ilẹ̀ ayé.”

Jẹnẹsisi 8

Jẹnẹsisi 8:12-22