Jẹnẹsisi 8:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Àdàbà náà fò pada ní ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ náà pẹlu ewé olifi tútù ní ẹnu rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni Noa ṣe mọ̀ pé omi ti fà lórí ilẹ̀.

Jẹnẹsisi 8

Jẹnẹsisi 8:7-15