Jẹnẹsisi 49:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ẹ̀yà Israẹli mejeejila ni a ti dárúkọ yìí, ati ohun tí baba wọn wí nígbà tí ó súre fún wọn. Ó súre tí ó tọ́ sí olukuluku fún un.

Jẹnẹsisi 49

Jẹnẹsisi 49:27-33