Jẹnẹsisi 48:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ tí o bá tún bí lẹ́yìn wọn, ìwọ ni o ni wọ́n, ninu ogún tí ó bá kan Manase ati Efuraimu ni wọn yóo ti pín.

Jẹnẹsisi 48

Jẹnẹsisi 48:2-12