Jẹnẹsisi 46:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Ati pé darandaran ni wọ́n, ìtọ́jú ẹran ọ̀sìn ni iṣẹ́ wọn, wọ́n sì kó gbogbo agbo mààlúù ati agbo ewúrẹ́, ati ohun gbogbo tí wọ́n ní lọ́wọ́ wá.

Jẹnẹsisi 46

Jẹnẹsisi 46:26-34