Jẹnẹsisi 45:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Israẹli ṣe bí ọba ti wí, Josẹfu fún wọn ní kẹ̀kẹ́ ẹlẹ́ṣin gẹ́gẹ́ bí àṣẹ Farao, ó sì fún wọn ní oúnjẹ tí wọn yóo máa jẹ lọ́nà.

Jẹnẹsisi 45

Jẹnẹsisi 45:18-23