Jẹnẹsisi 43:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin náà ṣe bí Josẹfu ti pàṣẹ fún un, ó sì mú àwọn ọkunrin náà wọ ilé Josẹfu lọ.

Jẹnẹsisi 43

Jẹnẹsisi 43:9-21