Jẹnẹsisi 43:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọkunrin náà bá gbé ẹ̀bùn náà, wọ́n sì mú ìlọ́po meji owó tí wọ́n nílò, ati Bẹnjamini, wọ́n lọ siwaju Josẹfu ní Ijipti.

Jẹnẹsisi 43

Jẹnẹsisi 43:11-20