Jẹnẹsisi 41:57 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ayé ni ó sì ń wá sọ́dọ̀ Josẹfu ní Ijipti tí wọ́n wá ra oúnjẹ, nítorí pé ìyàn náà mú gidigidi ní gbogbo ayé.

Jẹnẹsisi 41

Jẹnẹsisi 41:50-57