Jẹnẹsisi 4:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Kaini bá aya rẹ̀ lòpọ̀, ó lóyún, ó sì bí Enọku. Kaini lọ tẹ ìlú kan dó, ó sọ ìlú náà ní Enọku, tí í ṣe orúkọ ọmọ rẹ̀.

Jẹnẹsisi 4

Jẹnẹsisi 4:13-18