Jẹnẹsisi 36:25-32 BIBELI MIMỌ (BM)

25. Àwọn ọmọ Ana ni, Diṣoni ati Oholibama.

26. Àwọn ọmọ Diṣoni ni Hemdani, Eṣibani, Itirani, ati Kerani.

27. Àwọn ọmọ Eseri ni: Bilihani, Saafani, ati Akani.

28. Àwọn ọmọ Diṣani ni: Usi ati Arani.

29. Àwọn ìjòyè tí wọ́n ṣẹ̀ lára Hori nìwọ̀nyí: Lotani, Ṣobali, Sibeoni,

30. Diṣoni, Eseri, ati Diṣani. Àwọn ìjòyè ilẹ̀ Hori, gẹ́gẹ́ bí olórí ìdílé ìdílé wọn ní ilẹ̀ Seiri.

31. Àwọn ọba tí wọ́n jẹ ní ilẹ̀ Edomu kí ó tó di pé ẹnikẹ́ni jọba ní ilẹ̀ Israẹli nìwọ̀nyí:

32. Bela, ọmọ Beori jọba ní Edomu, orúkọ ìlú rẹ̀ ni Dinhaba.

Jẹnẹsisi 36