Jẹnẹsisi 35:27-29 BIBELI MIMỌ (BM)

27. Jakọbu pada sọ́dọ̀ Isaaki, baba rẹ̀, ní Mamure, ìlú yìí kan náà ni wọ́n ń pè ní Kiriati Ariba tabi Heburoni, níbi tí Abrahamu ati Isaaki gbé.

28. Isaaki jẹ́ ẹni ọgọsan-an (180) ọdún nígbà tí ó kú.

29. Ó dàgbà, ó darúgbó lọpọlọpọ kí ó tó kú. Àwọn ọmọ rẹ̀ mejeeji, Esau ati Jakọbu, sì sin ín.

Jẹnẹsisi 35