Jẹnẹsisi 32:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó rò ninu ara rẹ̀ pé bí Esau bá dé ọ̀dọ̀ ìpín tí ó wà níwájú, tí ó bá sì pa wọ́n run, ìpín kan tí ó kù yóo sá àsálà.

Jẹnẹsisi 32

Jẹnẹsisi 32:7-15