Jẹnẹsisi 32:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà ni Jakọbu fi sọ ibẹ̀ ní Penieli, ó ní, “Mo ti rí Ọlọrun lojukooju, sibẹ mo ṣì wà láàyè.”

Jẹnẹsisi 32

Jẹnẹsisi 32:21-32