Jẹnẹsisi 31:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ti àwa ati àwọn ọmọ wa ni ohun ìní gbogbo tí Ọlọrun gbà lọ́wọ́ baba wa jẹ́, nítorí náà, gbogbo ohun tí Ọlọrun bá sọ fún ọ láti ṣe, ṣe é.”

Jẹnẹsisi 31

Jẹnẹsisi 31:8-20