Jẹnẹsisi 30:43 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni Jakọbu ṣe di ọlọ́rọ̀ gidigidi, ó sì ní àwọn agbo ẹran ńláńlá, ọpọlọpọ iranṣẹbinrin ati iranṣẹkunrin, ràkúnmí ati kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́.

Jẹnẹsisi 30

Jẹnẹsisi 30:36-43