Jẹnẹsisi 30:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Jakọbu bá dáhùn pé, “Ìwọ náà mọ̀ bí mo ti sìn ọ́ ati bí àwọn ẹran ọ̀sìn rẹ ti ṣe dáradára lọ́wọ́ mi.

Jẹnẹsisi 30

Jẹnẹsisi 30:19-33