Jẹnẹsisi 30:21-23 BIBELI MIMỌ (BM)

21. Lẹ́yìn náà, ó bí obinrin kan, ó sọ ọ́ ní Dina.

22. Lẹ́yìn náà ni Ọlọrun ranti Rakẹli, ó gbọ́ ẹ̀bẹ̀ rẹ̀, ó sì ṣí inú rẹ̀.

23. Rakẹli lóyún, ó sì bí ọmọkunrin kan.

Jẹnẹsisi 30