Jẹnẹsisi 30:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Lea ní “Ọlọrun san ẹ̀san fún mi, nítorí pé mo fún ọkọ mi ní iranṣẹbinrin mi.” Ó bá sọ ọmọ náà ní Isakari.

Jẹnẹsisi 30

Jẹnẹsisi 30:15-19