Jẹnẹsisi 30:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò ìkórè ọkà alikama, Reubẹni bá wọn lọ sí oko, ó sì já èso mandiraki bọ̀ fún Lea ìyá rẹ̀. Nígbà tí Rakẹli rí i, ó bẹ Lea pé kí ó fún òun ninu èso mandiraki ọmọ rẹ̀.

Jẹnẹsisi 30

Jẹnẹsisi 30:11-20