Jẹnẹsisi 26:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Abimeleki bá dá a lóhùn pé, “Irú kí ni o dánwò sí wa yìí? Ǹjẹ́ bí ọ̀kan ninu àwọn eniyan wọnyi bá ti bá aya rẹ lòpọ̀ ńkọ́? O ò bá mú ẹ̀bi wá sórí wa.”

Jẹnẹsisi 26

Jẹnẹsisi 26:8-16