Jẹnẹsisi 26:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò kan, ìyàn ńlá kan mú ní ilẹ̀ náà, yàtọ̀ sí ìyàn tí ó mú ní ìgbà Abrahamu. Isaaki bá tọ Abimeleki ọba àwọn ará Filistini lọ ní Gerari.

Jẹnẹsisi 26

Jẹnẹsisi 26:1-3