Jẹnẹsisi 25:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn ọmọ náà dàgbà, Esau di ògbójú ọdẹ, a sì máa lọ sí oko ọdẹ nígbà gbogbo, ṣugbọn Jakọbu jẹ́ eniyan jẹ́jẹ́, ilé ni ó sì máa ń sábà gbé ní tirẹ̀.

Jẹnẹsisi 25

Jẹnẹsisi 25:20-32