Jẹnẹsisi 24:59 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá gbà pé kí Rebeka arabinrin wọn máa lọ, pẹlu olùtọ́jú rẹ̀ láti ìgbà èwe rẹ̀, ati iranṣẹ Abrahamu, pẹlu àwọn ọkunrin tí wọ́n bá a wá.

Jẹnẹsisi 24

Jẹnẹsisi 24:58-62