Jẹnẹsisi 23:11 BIBELI MIMỌ (BM)

“Rárá o! oluwa mi, gbọ́, mo fún ọ ní ilẹ̀ náà, ati ihò tí ó wà ninu rẹ̀, lójú gbogbo àwọn eniyan mi ni mo sì ti fún ọ, lọ sin aya rẹ sibẹ.”

Jẹnẹsisi 23

Jẹnẹsisi 23:2-20