Jẹnẹsisi 21:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Sara wí pé, “Ọlọ́run ti pa mí lẹ́rìn-ín, gbogbo ẹni tí ó bá gbọ́ ni yóo sì rẹ́rìn-ín.”

Jẹnẹsisi 21

Jẹnẹsisi 21:1-9