Jẹnẹsisi 20:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Ọlọrun mú kí n máa káàkiri kúrò ní ilé baba mi, mo wí fún un pé, ‘Oore kan tí o lè ṣe fún mi nìyí: níbi gbogbo tí a bá dé, wí fún wọn pé, arakunrin rẹ ni mí.’ ”

Jẹnẹsisi 20

Jẹnẹsisi 20:7-14