Jẹnẹsisi 18:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Abrahamu tún sọ fún OLUWA pé, “Jọ̀wọ́, dárí àfojúdi mi jì mí, èmi eniyan lásán, nítorí n kò ní ẹ̀tọ́ láti bá ìwọ OLUWA jiyàn?

Jẹnẹsisi 18

Jẹnẹsisi 18:21-33