Jẹnẹsisi 16:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Wò ó! oyún tí ó wà ninu rẹ, ọkunrin ni o óo fi bí, o óo sọ ọmọ náà ní Iṣimaeli, nítorí OLUWA ti rí gbogbo ìyà tí ń jẹ ọ́.

Jẹnẹsisi 16

Jẹnẹsisi 16:6-16