Jẹnẹsisi 16:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Sarai, aya Abramu, kò bímọ fún un. Ṣugbọn ó ní ẹrubinrin ará Ijipti kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Hagari.

Jẹnẹsisi 16

Jẹnẹsisi 16:1-6