Jẹnẹsisi 11:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Eberi tún gbé ojilenirinwo ó dín mẹ́wàá (430) ọdún sí i láyé lẹ́yìn tí ó bí Pelegi tán, ó tún bí àwọn ọmọ mìíràn lọkunrin ati lobinrin.

Jẹnẹsisi 11

Jẹnẹsisi 11:7-26