Jẹnẹsisi 10:25-29 BIBELI MIMỌ (BM)

25. Àwọn ọmọkunrin meji ni Eberi bí, orúkọ ekinni ni Pelegi, nítorí pé ní ìgbà tirẹ̀ ni ayé pínyà, orúkọ ekeji ni Jokitani.

26. Jokitani ni baba Alimodadi, Ṣelefu, Hasamafeti, Jera,

27. Hadoramu, Usali, Dikila,

28. Obali, Abimaeli,

29. Ṣeba, Ofiri, Hafila, ati Jobabu, àwọn ni ọmọ Jokitani.

Jẹnẹsisi 10