Jẹnẹsisi 1:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sọ ìyàngbẹ ilẹ̀ náà ní ilẹ̀, ó sì sọ omi tí ó wọ́jọ pọ̀ ní òkun. Ó wò ó, ó sì rí i pé ó dára.

Jẹnẹsisi 1

Jẹnẹsisi 1:1-12