Ìwé Òwe 8:1-4 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ọgbọ́n ń pe eniyan,òye ń pariwo.

2. Ó dúró ní ibi tí ó ga lẹ́bàá ọ̀nà,ati ní ojú ọ̀nà tóóró,

3. ó ń kígbe lóhùn rara lẹ́nu ibodè àtiwọ ìlú,ó ń ké ní ẹnu ọ̀nà àbáwọlé pẹlu,ó ń wí pé:

4. “Ẹ̀yin eniyan ni mò ń pè,gbogbo ọmọ eniyan ni mò ń ké sí.

Ìwé Òwe 8